Lori eto wa to’oni, a wo igboro lo lori oro Bamise Ayanwola, arabinrin to so nu lehin ti o wo oko BRT ni Lekki. Oku omo ni awon obi ri ni ojo Aje to koja yi. Kini iro’ngba yi si isele yi.
Read More
[FÍDÍÒ] Ojú kálé: Àwọn ọmọ Nàìjíríà fi èrò wọn hàn nípa ikú tó pa Bámiṣé Àyánwọ̀lé
Leave a Comment
Leave a Comment