Eni àádọ́rin ọdún, Amodu Bakare, ti awon Fulani ge ni owo mejeeji ba wa soro ni ilu Itasa ni ipinle Oyo, nipa bi isele na se sele.
Oba alade ilu Itasa, Oba Michael Oyediran, na salaye eyi ti won mo nipa isele na.
Asi tun ba olori awon Fulani/Hausa to was ni ilu Itasa soro lori isele na.
Copyright PUNCH.
All rights reserved. This material, and other digital content on this website, may not be reproduced, published, broadcast, rewritten or redistributed in whole or in part without prior express written permission from PUNCH.
Contact: [email protected]