27th May 2023
A bá àwọn ará ìlú sọ̀rọ̀ nípa èrò wọn lórí ìṣèjọba ààrẹ Muhammadu Buhari. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló fi ẹ̀dùn ọkàn wọn hàn nípa àṣeètó ààrẹ Buhari.
Oníkálukú sọ àfojúsùn wọn fún ààrẹ tuntun tí a dìbò yàn, tí wọ́n sì rọ̀ wọ́n pé kí wọ́n ṣe ohun tó tọ́ fún ará ìlú kí wọ́n lè rántí wọn sí rere.
All rights reserved. This material, and other digital content on this website, may not be reproduced, published, broadcast, rewritten or redistributed in whole or in part without prior express written permission from PUNCH.
Contact: [email protected]