A bá arábìnrin Fatimah Aderohunmu tó ní ìpènijà ‘Muscular Dystrophy’ sọ̀rọ̀ nípa bí àìlera rẹ̀ ti bẹ̀rẹ̀. Ó ṣàlàyé ohun tí àìsàn náà jẹ́ àti bí ó ṣe ti ń bá a yí láti ọdún díẹ̀ sẹ́yìn. Ó sì ṣàlàyé bí ó ṣe kọ̀wé nípa rẹ̀ láti fi ró àwọn Onípènijà akẹgbẹ́ rẹ̀ lágbára.
Read More
Mi ò gbàgbọ́ pé kò sí ìwòsàn fún àìlera mi — Òǹkọ̀wé Onípènijà
Leave a Comment
Leave a Comment