A bá àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ nípa ohun tí wọ́n rí sí ìgbésẹ̀ ìjọba àpapọ̀ láti ya owó tí kò dín ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta bílíọ́nù náírà sọ́tọ̀ gẹ́gẹ́ bí Ìrànwọ́ palétíífù fún ará ìlú.
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló fara mọ́ ìgbésẹ̀ ìjọba yìí, àwọn mìíràn sì dábàá pé kí á padà sí bí a ṣe wà tẹ́lẹ̀, kí ìjọba àpapọ̀ ó dá ìrànwọ́ orí epo padà kí ó lè mú ìdẹkùn bá mẹ̀kúnnù.
All rights reserved. This material, and other digital content on this website, may not be reproduced, published, broadcast, rewritten or redistributed in whole or in part without prior express written permission from PUNCH.
Contact: [email protected]