A bá àwọn ará ìlú sọ̀rọ̀ nípa ọ̀rọ̀ ètò ẹ̀yáwó akẹ́kọ̀ọ́ lọ́dọ̀ ìjọba láti kàwé nílé-ìwé ìjọba. Ọ̀pọ̀ èèyàn ló bẹnu àtẹ́ lu ìgbésẹ̀ yìí pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdí.
Àwọn ará ìlú tún mẹ́nu ba ọ̀rọ̀ owó ilé-ìwé tó gbé pẹ́ẹ́lí sí i ní àwọn ilé-ìwé ìjọba kan, wọ́n sì ràwọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba kí wọ́n ṣàánú mẹ̀kúnnù tí wọ́n ń forí wọn fọ́ àgbọn nígbà gbogbo.
All rights reserved. This material, and other digital content on this website, may not be reproduced, published, broadcast, rewritten or redistributed in whole or in part without prior express written permission from PUNCH.
Contact: [email protected]