FÍDÍÒ: Ojú kálé: Àwọn ọmọ Nàìjíríà fi ẹ̀dùn ọkàn wọn hàn lórí àjálù tó ṣẹlẹ̀ ní Ọ̀wọ̀, ìpínlẹ̀ Oǹdó
A bá àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ nípa àjálù tó ṣẹlẹ̀ ní Ọ̀wọ̀,…
FÍDÍÒ: Ọ̀rọ̀ Kàbìtì: Bí mo ṣe pàdánù ọwọ́ mi méjèèjì lẹ́yìn ìkọlù Fúlàní -Bàbá àgbẹ̀ ẹni àádọ́rin ọdún
Eni àádọ́rin ọdún, Amodu Bakare, ti awon Fulani ge ni owo mejeeji…
[FÍDÍÒ] Ojú Kálé: Ẹ gbọ́ èrò àwọn ọmọ nàìjíríà nípa fídíò àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Chrisland College tó ń tàn ká
Woman speaking with our correspondent. A bá àwọn ọmọ Nàìjíríà sọ̀rọ̀ nípa…
[FÍDÍÒ] Èdè wa ni: Ẹ pàdé Babatúndé Pópóọlá, akẹ́kọ̀ọ́ Yorùbá tó peregedé jùlọ ní ẹka ẹ̀kọ́ imọ̀ ẹ̀dá èdè ní UNILAG
Akẹ́kọ̀ọ́ Babatúndé Pópóọlá A lọ sí fásitì Èkó láti lọ ṣe ìfọ́rọ̀wérọ̀…
[FÍDÍÒ] Ọ̀rọ̀ kàbìtì: Ọwọ́ tẹ afurasí agbénipa méje tí wọ́n ń ta ẹ̀yà ara ènìyàn
Victim of kidnapping in Ogun Awon afurasí agbénipa méje ni owo agbofinro…
[FÍDÍÒ] Èdè wa ni: Ẹ pàdé Adékọ́lá Wikipedia tó ń dá àwọn ènìyàn lárayá pẹ̀lú ìpolówó ọjà rẹ̀
Ogbeni Adekola Ademuyiwa ti gbogbo eniyan mo si Adekola Wikipedia ba wa…
[FÍDÍÒ] Ojú kálé: Àwọn ọmọ Nàìjíríà fi èrò wọn hàn nípa ikú tó pa Bámiṣé Àyánwọ̀lé
Lori eto wa to’oni, a wo igboro lo lori oro Bamise Ayanwola,…
[FÍDÍÒ] Ojú Kálé: Àwọn ọmọ Nàìjíríà fi Èrò wọn hàn nípa ọ̀rọ̀ Sofiat Kẹ́hìndé tí wọ́n bẹ́ lórí láti fi sòògùn owó l’Ábẹ́òkuta
Published 2 February 2022 Lórí ètò Ojú Kálé, Ojú Káko tòní, a…