Ẹ Pàdé Olorì Sports Tó Ń Fi Ẹ̀fẹ̀ Ṣ’àtúpalẹ̀ Eré Ìdárayá Lédè Yorùbá
A ṣe àbẹ̀wò sí arábìnrin Adérónkẹ́ Adéṣọlá Olorì Sports ní ilé iṣẹ́…
Ẹ Pàdé Ọ̀dọ́mọdébìnrin Ayanwura Tó Ń Fi Ìlù Lílù Yin Olódùmarè
A bá Ọ̀dọ́mọdébìnrin Sofiyat Ọláídé tí àwọn èèyàn mọ̀ sí Àyánwúrà àti…
Ẹ pàdé Owólabí Àjàsá tó n kó ipa olọ́pàá nínú awọn sinimá agbéléwò Yorùbá
A bá ọ̀gbẹ́ni Owólabí Àjàsá sọ̀rọ̀ lórí ipa Ọlọ́pàá tó máa ń…
Èdè wa ni: Ẹ pàdé olọ́runtọ́ba, olùsin ajá tó n bá awọn ajá rẹ̀ s’ọ̀rọ̀ l’édè Yorùbá
A bá olùsin ajá, Ọlọ́runtọ́ba, sọ̀rọ̀ lórí ìlànà tí ó ń lò…
Èdè wa ni: Ẹ pàdé Àròjinlẹ̀ tó ń dá àwọn ènìyàn lẹ́kọ̀ọ́ nípa ẹranko lédè Yorùbá
A bá ògbóntarìgì gbédègbẹyọ tí àwọn èèyàn mọ̀ sí Àròjinlẹ̀ sọ̀rọ̀ nípa…
Èdè wa ni: Ẹ pàdé Omọ́wálé, tó há awọn iwé itàn D. O. Fágúnwà sórí
A ṣe àbẹ̀wò sí bàbá Ọmọ́wálé Òdúmọ ti wọ́n há àwọn ìwé…
Èdè wa ni: Ẹ pàdé Tiago Ìṣọ̀lá àti ìyá rẹ̀ láti ìlú Pọ́túgà tí wọ́n ń náání èdè àti àṣà Yorùbá
Tiago Gomes, ti o n pe ara re ni Oyinbo Ibile bawa…
[FÍDÍÒ] Èdè wa ni: Ẹ pàdé Babatúndé Pópóọlá, akẹ́kọ̀ọ́ Yorùbá tó peregedé jùlọ ní ẹka ẹ̀kọ́ imọ̀ ẹ̀dá èdè ní UNILAG
Akẹ́kọ̀ọ́ Babatúndé Pópóọlá A lọ sí fásitì Èkó láti lọ ṣe ìfọ́rọ̀wérọ̀…
[FÍDÍÒ] Èdè wa ni: Ẹ pàdé Adékọ́lá Wikipedia tó ń dá àwọn ènìyàn lárayá pẹ̀lú ìpolówó ọjà rẹ̀
Ogbeni Adekola Ademuyiwa ti gbogbo eniyan mo si Adekola Wikipedia ba wa…