Wòli láti Gambia gbé owó, ẹ̀rọ ìbànisọ̀rọ̀ àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ sá lọ lẹ́yìn ìsọjí n’Íbàdàn.
A lọ sí àgbègbè Apọ́nrin, Agbowó, ìlú Ìbàdàn, níbi tí oníwàásù Owen…
Èdè wa ni: Ẹ pàdé olọ́runtọ́ba, olùsin ajá tó n bá awọn ajá rẹ̀ s’ọ̀rọ̀ l’édè Yorùbá
A bá olùsin ajá, Ọlọ́runtọ́ba, sọ̀rọ̀ lórí ìlànà tí ó ń lò…
Ọ̀rọ̀ kàbìtì: Bí obìnrin ṣe jí ọmọ gbé láti Oǹdó wá fún ọkọ rẹ̀ ní Ṣàgámù
A ṣe àbẹ̀wò sí olú ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Oǹdó, níbi tí ọwọ́…
Èdè wa ni: Má ṣe ri ẹ̀bùn àtọ̀runwá rẹ mọ́lẹ̀ – Ọ̀dọ́mọdébìnrin onílù Àyàngbémisọ́lá
By Our Reporters 30th June 2022 A bá Lewis Àyángbémisọ́lá sọ̀rọ̀ nípa…
Èdè wa ni: Ẹ pàdé Tiago Ìṣọ̀lá àti ìyá rẹ̀ láti ìlú Pọ́túgà tí wọ́n ń náání èdè àti àṣà Yorùbá
Tiago Gomes, ti o n pe ara re ni Oyinbo Ibile bawa…
[FÍDÍÒ] Èdè wa ni: Ẹ pàdé Adékọ́lá Wikipedia tó ń dá àwọn ènìyàn lárayá pẹ̀lú ìpolówó ọjà rẹ̀
Ogbeni Adekola Ademuyiwa ti gbogbo eniyan mo si Adekola Wikipedia ba wa…